Sáàmù 41:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kódà, ẹni tó wà ní àlàáfíà pẹ̀lú mi, tí mo fọkàn tán,+Ẹni tí a jọ ń jẹun, ti jìn mí lẹ́sẹ̀.*+