Sáàmù 27:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Má fi mí lé ọwọ́ àwọn elénìní mi,*+Nítorí pé àwọn ẹlẹ́rìí èké ti dìde sí mi,+Wọ́n sì ń halẹ̀ pé àwọn máa ṣe mí léṣe. Sáàmù 35:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn ẹlẹ́rìí èké jáde wá,+Wọ́n ń bi mí ní àwọn ohun tí mi ò mọ̀.
12 Má fi mí lé ọwọ́ àwọn elénìní mi,*+Nítorí pé àwọn ẹlẹ́rìí èké ti dìde sí mi,+Wọ́n sì ń halẹ̀ pé àwọn máa ṣe mí léṣe.