Lúùkù 22:63, 64 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Àwọn ọkùnrin tó mú Jésù wá bẹ̀rẹ̀ sí í fi Jésù ṣe yẹ̀yẹ́,+ wọ́n ń lù ú;+ 64 lẹ́yìn tí wọ́n sì fi nǹkan bò ó lójú, wọ́n ń bi í pé: “Sọ tẹ́lẹ̀! Ta lẹni tó gbá ọ?”
63 Àwọn ọkùnrin tó mú Jésù wá bẹ̀rẹ̀ sí í fi Jésù ṣe yẹ̀yẹ́,+ wọ́n ń lù ú;+ 64 lẹ́yìn tí wọ́n sì fi nǹkan bò ó lójú, wọ́n ń bi í pé: “Sọ tẹ́lẹ̀! Ta lẹni tó gbá ọ?”