15Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà pẹ̀lú àwọn akọ̀wé òfin, àní gbogbo Sàhẹ́ndìrìn, gbìmọ̀ pọ̀, wọ́n de Jésù, wọ́n mú un lọ, wọ́n sì fà á lé Pílátù lọ́wọ́.+
66 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin, kóra jọ,+ wọ́n sì mú un lọ sínú gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn wọn, wọ́n sọ pé: