-
1 Tẹsalóníkà 2:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ẹ̀yin ará ń fara wé àwọn ìjọ Ọlọ́run tó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù ní Jùdíà, nítorí àwọn ará ìlú yín ń fìyà jẹ yín + bí àwọn Júù ṣe ń fìyà jẹ àwọn náà, 15 kódà wọ́n pa Jésù Olúwa+ àti àwọn wòlíì, wọ́n sì ṣe inúnibíni sí wa.+ Bákan náà, wọn ò ṣe ohun tó wu Ọlọ́run, wọn ò sì ní ire àwọn èèyàn lọ́kàn,
-