Jòhánù 19:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ọmọ ogun fi ẹ̀gún hun adé, wọ́n dé e sí i lórí, wọ́n sì wọ aṣọ aláwọ̀ pọ́pù fún un,+ 3 wọ́n ń wá sọ́dọ̀ rẹ̀ ṣáá, wọ́n sì ń sọ pé: “A kí ọ o,* ìwọ Ọba Àwọn Júù!” Wọ́n sì ń gbá a létí léraléra.+
2 Àwọn ọmọ ogun fi ẹ̀gún hun adé, wọ́n dé e sí i lórí, wọ́n sì wọ aṣọ aláwọ̀ pọ́pù fún un,+ 3 wọ́n ń wá sọ́dọ̀ rẹ̀ ṣáá, wọ́n sì ń sọ pé: “A kí ọ o,* ìwọ Ọba Àwọn Júù!” Wọ́n sì ń gbá a létí léraléra.+