Sáàmù 22:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ó fi ara rẹ̀ lé Jèhófà lọ́wọ́. Kí Ó gbà á sílẹ̀ báyìí! Kí Ó gbà á là, ṣebí ó fẹ́ràn Rẹ̀ gan-an!”+