-
Máàkù 15:35, 36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Nígbà tí àwọn kan lára àwọn tó dúró nítòsí gbọ́ èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Ẹ wò ó! Ó ń pe Èlíjà.” 36 Ẹnì kan wá sáré lọ rẹ kànrìnkàn sínú wáìnì kíkan, ó fi sórí ọ̀pá esùsú, ó sì fún un pé kó mu ún,+ ó ní: “Ẹ fi sílẹ̀! Ká wò ó bóyá Èlíjà máa wá gbé e sọ̀ kalẹ̀.”
-