Jòhánù 19:40, 41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Torí náà, wọ́n gbé òkú Jésù, wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀* dì í pẹ̀lú àwọn èròjà tó ń ta sánsán náà,+ bí àwọn Júù ṣe máa ń sìnkú. 41 Ó ṣẹlẹ̀ pé ọgbà kan wà níbi tí wọ́n ti pa á,* ibojì* tuntun+ kan sì wà nínú ọgbà náà, tí wọn ò tẹ́ ẹnì kankan sí rí.
40 Torí náà, wọ́n gbé òkú Jésù, wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀* dì í pẹ̀lú àwọn èròjà tó ń ta sánsán náà,+ bí àwọn Júù ṣe máa ń sìnkú. 41 Ó ṣẹlẹ̀ pé ọgbà kan wà níbi tí wọ́n ti pa á,* ibojì* tuntun+ kan sì wà nínú ọgbà náà, tí wọn ò tẹ́ ẹnì kankan sí rí.