Àìsáyà 40:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: “Ẹ tún ọ̀nà Jèhófà ṣe!*+ Ẹ la ọ̀nà tó tọ́ + gba inú aṣálẹ̀ fún Ọlọ́run wa.+ Jòhánù 1:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó sọ pé: “Èmi ni ohùn ẹni tó ń ké nínú aginjù pé, ‘Ẹ mú ọ̀nà Jèhófà* tọ́,’+ bí wòlíì Àìsáyà ṣe sọ.”+
3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: “Ẹ tún ọ̀nà Jèhófà ṣe!*+ Ẹ la ọ̀nà tó tọ́ + gba inú aṣálẹ̀ fún Ọlọ́run wa.+
23 Ó sọ pé: “Èmi ni ohùn ẹni tó ń ké nínú aginjù pé, ‘Ẹ mú ọ̀nà Jèhófà* tọ́,’+ bí wòlíì Àìsáyà ṣe sọ.”+