Mátíù 13:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Tí ẹnikẹ́ni bá gbọ́ ọ̀rọ̀ Ìjọba náà, àmọ́ tí kò yé e, ẹni burúkú náà+ á wá, á sì já ohun tí a gbìn sínú ọkàn rẹ̀ gbà lọ; èyí ni irúgbìn tó bọ́ sí etí ọ̀nà.+ Lúùkù 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ti etí ọ̀nà ni àwọn tó gbọ́, tí Èṣù wá lẹ́yìn náà, tó sì mú ọ̀rọ̀ náà kúrò nínú ọkàn wọn, kí wọ́n má bàa gbà gbọ́, kí wọ́n sì rí ìgbàlà.+
19 Tí ẹnikẹ́ni bá gbọ́ ọ̀rọ̀ Ìjọba náà, àmọ́ tí kò yé e, ẹni burúkú náà+ á wá, á sì já ohun tí a gbìn sínú ọkàn rẹ̀ gbà lọ; èyí ni irúgbìn tó bọ́ sí etí ọ̀nà.+
12 Àwọn ti etí ọ̀nà ni àwọn tó gbọ́, tí Èṣù wá lẹ́yìn náà, tó sì mú ọ̀rọ̀ náà kúrò nínú ọkàn wọn, kí wọ́n má bàa gbà gbọ́, kí wọ́n sì rí ìgbàlà.+