Sáàmù 78:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Màá la ẹnu mi láti pa òwe. Màá pa àwọn àlọ́ tó ti wà tipẹ́tipẹ́.+