Mátíù 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Èṣù wá fi í sílẹ̀,+ sì wò ó! àwọn áńgẹ́lì wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ìránṣẹ́ fún un.+