ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Lúùkù 8:28-30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Bó ṣe rí Jésù, ó kígbe, ó sì wólẹ̀ síwájú rẹ̀, ó wá ké jáde pé: “Kí ló pa wá pọ̀, Jésù Ọmọ Ọlọ́run Gíga Jù Lọ? Mo bẹ̀ ọ́, má ṣe dá mi lóró.”+ 29 (Torí Jésù ti ń pàṣẹ fún ẹ̀mí àìmọ́ náà pé kó jáde lára ọkùnrin náà. Ẹ̀mí náà ti gbá ọkùnrin náà mú lọ́pọ̀ ìgbà,*+ léraléra sì ni wọ́n fi ẹ̀wọ̀n àti ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ dè é, tí wọ́n sì ń ṣọ́ ọ, àmọ́ ó máa ń já àwọn ìdè náà, ẹ̀mí èṣù náà á sì mú kó lọ sí àwọn ibi tó dá.) 30 Jésù bi í pé: “Kí lorúkọ rẹ?” Ó sọ pé: “Líjíónì,” torí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀mí èṣù ti wọ inú rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́