ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Lúùkù 8:38, 39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Àmọ́ ọkùnrin tí àwọn ẹ̀mí èṣù jáde lára rẹ̀ ń bẹ̀ ẹ́ ṣáá pé òun fẹ́ bá a lọ, ṣùgbọ́n ó ní kí ọkùnrin náà máa lọ, ó ní:+ 39 “Pa dà sílé, kí o sì máa ròyìn ohun tí Ọlọ́run ṣe fún ọ.” Torí náà, ó lọ, ó ń kéde ohun tí Jésù ṣe fún un káàkiri gbogbo ìlú náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́