Lúùkù 8:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Nígbà tí Jésù pa dà dé, àwọn èrò náà tẹ́wọ́ gbà á tinútinú, torí gbogbo wọn ti ń retí rẹ̀.+