-
Lúùkù 4:40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
40 Àmọ́ nígbà tí oòrùn ń wọ̀, gbogbo àwọn tí èèyàn wọn ń ṣàìsàn, tí wọ́n ní oríṣiríṣi àrùn, mú wọn wá sọ́dọ̀ rẹ̀. Bó ṣe ń gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn, ó ń wò wọ́n sàn.+
-