Lúùkù 8:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Àmọ́ gbogbo èèyàn ń sunkún, wọ́n sì ń lu ara wọn bí wọ́n ṣe ń dárò torí ọmọ náà. Torí náà, ó sọ pé: “Ẹ má sunkún mọ́,+ torí kò kú, ó ń sùn ni.”+ Jòhánù 11:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, ó fi kún un pé: “Lásárù ọ̀rẹ́ wa ti sùn,+ àmọ́ mò ń rìnrìn àjò lọ síbẹ̀ kí n lè jí i.”
52 Àmọ́ gbogbo èèyàn ń sunkún, wọ́n sì ń lu ara wọn bí wọ́n ṣe ń dárò torí ọmọ náà. Torí náà, ó sọ pé: “Ẹ má sunkún mọ́,+ torí kò kú, ó ń sùn ni.”+
11 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, ó fi kún un pé: “Lásárù ọ̀rẹ́ wa ti sùn,+ àmọ́ mò ń rìnrìn àjò lọ síbẹ̀ kí n lè jí i.”