Mátíù 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àtìgbà yẹn lọ ni Jésù ti bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù, tó sì ń sọ pé: “Ẹ ronú pìwà dà, torí Ìjọba ọ̀run ti sún mọ́lé.”+
17 Àtìgbà yẹn lọ ni Jésù ti bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù, tó sì ń sọ pé: “Ẹ ronú pìwà dà, torí Ìjọba ọ̀run ti sún mọ́lé.”+