Mátíù 13:57 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kọsẹ̀ nítorí rẹ̀.+ Ṣùgbọ́n Jésù sọ fún wọn pé: “Wòlíì máa ń níyì, àmọ́ kì í gbayì ní ìlú rẹ̀ àti ní ilé òun fúnra rẹ̀.”+ Lúùkù 4:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí náà, ó sọ pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín pé kò sí wòlíì tí wọ́n máa ń tẹ́wọ́ gbà ní ìlú rẹ̀.+ Jòhánù 4:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Jésù fúnra rẹ̀ jẹ́rìí sí i pé wòlíì kì í gbayì ní ìlú rẹ̀.+
57 Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kọsẹ̀ nítorí rẹ̀.+ Ṣùgbọ́n Jésù sọ fún wọn pé: “Wòlíì máa ń níyì, àmọ́ kì í gbayì ní ìlú rẹ̀ àti ní ilé òun fúnra rẹ̀.”+