Mátíù 10:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ má ṣe wá wúrà, fàdákà tàbí bàbà sínú àmùrè tí ẹ̀ ń kó owó sí,+ 10 tàbí àpò oúnjẹ fún ìrìn àjò náà tàbí aṣọ méjì,* bàtà tàbí ọ̀pá,+ torí oúnjẹ tọ́ sí òṣìṣẹ́.+
9 Ẹ má ṣe wá wúrà, fàdákà tàbí bàbà sínú àmùrè tí ẹ̀ ń kó owó sí,+ 10 tàbí àpò oúnjẹ fún ìrìn àjò náà tàbí aṣọ méjì,* bàtà tàbí ọ̀pá,+ torí oúnjẹ tọ́ sí òṣìṣẹ́.+