-
Lúùkù 10:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Lẹ́yìn náà, àwọn àádọ́rin (70) náà pa dà dé tayọ̀tayọ̀, wọ́n ń sọ pé: “Olúwa, àwọn ẹ̀mí èṣù pàápàá tẹrí ba fún wa torí pé a lo orúkọ rẹ.”+
-