Mátíù 16:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wọ́n sọ pé: “Àwọn kan sọ pé Jòhánù Arinibọmi,+ àwọn míì ń sọ pé Èlíjà,+ àwọn míì sì ń sọ pé Jeremáyà tàbí ọ̀kan lára àwọn wòlíì.” Máàkù 8:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Wọ́n sọ fún un pé: “Jòhánù Arinibọmi,+ àmọ́ àwọn míì ń sọ pé Èlíjà,+ àwọn míì sì ń sọ pé ọ̀kan lára àwọn wòlíì.”
14 Wọ́n sọ pé: “Àwọn kan sọ pé Jòhánù Arinibọmi,+ àwọn míì ń sọ pé Èlíjà,+ àwọn míì sì ń sọ pé Jeremáyà tàbí ọ̀kan lára àwọn wòlíì.”
28 Wọ́n sọ fún un pé: “Jòhánù Arinibọmi,+ àmọ́ àwọn míì ń sọ pé Èlíjà,+ àwọn míì sì ń sọ pé ọ̀kan lára àwọn wòlíì.”