-
Mátíù 21:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Àmọ́ tí a bá sọ pé, ‘Látọ̀dọ̀ èèyàn,’ ẹ̀rù àwọn èrò yìí ń bà wá, torí wòlíì ni gbogbo wọn ka Jòhánù sí.”