Lúùkù 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nígbà tí àwọn àpọ́sítélì dé, wọ́n ròyìn gbogbo ohun tí wọ́n ṣe fún Jésù.+ Ó wá mú wọn lọ, wọ́n sì kúrò níbẹ̀ láwọn nìkan lọ sí ìlú kan tó ń jẹ́ Bẹtisáídà.+
10 Nígbà tí àwọn àpọ́sítélì dé, wọ́n ròyìn gbogbo ohun tí wọ́n ṣe fún Jésù.+ Ó wá mú wọn lọ, wọ́n sì kúrò níbẹ̀ láwọn nìkan lọ sí ìlú kan tó ń jẹ́ Bẹtisáídà.+