Jòhánù 6:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Lẹ́yìn náà, Jésù gbéra lọ sí òdìkejì Òkun Gálílì tàbí Tìbéríà.+ 2 Èrò rẹpẹtẹ ń tẹ̀ lé e ṣáá,+ torí wọ́n ń kíyè sí àwọn iṣẹ́ ìyanu tó ń ṣe, bó ṣe ń wo àwọn aláìsàn sàn.+
6 Lẹ́yìn náà, Jésù gbéra lọ sí òdìkejì Òkun Gálílì tàbí Tìbéríà.+ 2 Èrò rẹpẹtẹ ń tẹ̀ lé e ṣáá,+ torí wọ́n ń kíyè sí àwọn iṣẹ́ ìyanu tó ń ṣe, bó ṣe ń wo àwọn aláìsàn sàn.+