Jòhánù 6:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tí Jésù gbójú sókè, tó sì rí i pé èrò rẹpẹtẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ òun, ó sọ fún Fílípì pé: “Ibo la ti máa ra búrẹ́dì táwọn èèyàn yìí máa jẹ?”+
5 Nígbà tí Jésù gbójú sókè, tó sì rí i pé èrò rẹpẹtẹ ń bọ̀ lọ́dọ̀ òun, ó sọ fún Fílípì pé: “Ibo la ti máa ra búrẹ́dì táwọn èèyàn yìí máa jẹ?”+