-
Mátíù 14:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Àmọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Jésù sọ fún wọn pé: “Ẹ mọ́kàn le! Èmi ni; ẹ má bẹ̀rù.”+
-
-
Jòhánù 6:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àmọ́ ó sọ fún wọn pé: “Èmi ni; ẹ má bẹ̀rù!”+
-