Mátíù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Kí ló dé tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ ò tẹ̀ lé àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ àwọn èèyàn àtijọ́? Bí àpẹẹrẹ, wọn kì í wẹ* ọwọ́ wọn tí wọ́n bá fẹ́ jẹun.”+
2 “Kí ló dé tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ ò tẹ̀ lé àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ àwọn èèyàn àtijọ́? Bí àpẹẹrẹ, wọn kì í wẹ* ọwọ́ wọn tí wọ́n bá fẹ́ jẹun.”+