Mátíù 15:7-9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ̀yin alágàbàgebè, bí Àìsáyà ṣe sọ tẹ́lẹ̀ nípa yín ló rí gẹ́lẹ́, nígbà tó sọ pé:+ 8 ‘Àwọn èèyàn yìí ń fi ètè wọn bọlá fún mi, àmọ́ ọkàn wọn jìnnà gan-an sí mi. 9 Lásán ni wọ́n ń jọ́sìn mi, torí pé àṣẹ èèyàn ni ẹ̀kọ́ tí wọ́n fi ń kọ́ni.’”+
7 Ẹ̀yin alágàbàgebè, bí Àìsáyà ṣe sọ tẹ́lẹ̀ nípa yín ló rí gẹ́lẹ́, nígbà tó sọ pé:+ 8 ‘Àwọn èèyàn yìí ń fi ètè wọn bọlá fún mi, àmọ́ ọkàn wọn jìnnà gan-an sí mi. 9 Lásán ni wọ́n ń jọ́sìn mi, torí pé àṣẹ èèyàn ni ẹ̀kọ́ tí wọ́n fi ń kọ́ni.’”+