Mátíù 19:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ni Pétérù bá fèsì pé: “Wò ó! A ti fi ohun gbogbo sílẹ̀, a sì tẹ̀ lé ọ; kí ló máa wá jẹ́ tiwa?”+ Lúùkù 5:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Wọ́n wá dá àwọn ọkọ̀ ojú omi náà pa dà sórí ilẹ̀, wọ́n pa ohun gbogbo tì, wọ́n sì tẹ̀ lé e.+