-
Ìṣe 14:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Nígbà tí ọ̀pọ̀ èèyàn rí ohun tí Pọ́ọ̀lù ṣe, wọ́n gbé ohùn wọn sókè, wọ́n sì fi èdè Likaóníà sọ pé: “Àwọn ọlọ́run ti gbé àwọ̀ èèyàn wọ̀, wọ́n sì ti sọ̀ kalẹ̀ wá bá wa!”+
-