Máàkù 6:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ó wá mú búrẹ́dì márùn-ún àti ẹja méjì náà, ó wo ojú ọ̀run, ó sì súre.+ Lẹ́yìn náà, ó bu àwọn búrẹ́dì náà sí wẹ́wẹ́, ó bẹ̀rẹ̀ sí í fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn pé kí wọ́n gbé e síwájú àwọn èèyàn náà, ó sì pín ẹja méjì náà fún gbogbo wọn.
41 Ó wá mú búrẹ́dì márùn-ún àti ẹja méjì náà, ó wo ojú ọ̀run, ó sì súre.+ Lẹ́yìn náà, ó bu àwọn búrẹ́dì náà sí wẹ́wẹ́, ó bẹ̀rẹ̀ sí í fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn pé kí wọ́n gbé e síwájú àwọn èèyàn náà, ó sì pín ẹja méjì náà fún gbogbo wọn.