Mátíù 15:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Níkẹyìn, lẹ́yìn tó ní kí àwọn èrò náà máa lọ, ó wọ ọkọ̀ ojú omi, ó sì wá sí agbègbè Mágádánì.+