Mátíù 12:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Àwọn kan lára àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn Farisí wá fún un lésì pé: “Olùkọ́, a fẹ́ rí àmì kan látọ̀dọ̀ rẹ.”+ Jòhánù 6:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Torí náà, wọ́n sọ fún un pé: “Iṣẹ́ àmì wo lo máa ṣe,+ ká lè rí i, ká sì gbà ọ́ gbọ́? Iṣẹ́ wo lo máa ṣe?
38 Àwọn kan lára àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn Farisí wá fún un lésì pé: “Olùkọ́, a fẹ́ rí àmì kan látọ̀dọ̀ rẹ.”+
30 Torí náà, wọ́n sọ fún un pé: “Iṣẹ́ àmì wo lo máa ṣe,+ ká lè rí i, ká sì gbà ọ́ gbọ́? Iṣẹ́ wo lo máa ṣe?