Máàkù 6:56 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 56 Níbikíbi tó bá sì ti wọ àwọn abúlé, ìlú tàbí ìgbèríko, wọ́n máa gbé àwọn aláìsàn sí àwọn ibi tí wọ́n ti ń tajà, wọ́n á sì bẹ̀ ẹ́ pé kó jẹ́ kí wọ́n fọwọ́ kan wajawaja etí aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀ lásán.+ Ara gbogbo àwọn tó fọwọ́ kàn án sì yá.
56 Níbikíbi tó bá sì ti wọ àwọn abúlé, ìlú tàbí ìgbèríko, wọ́n máa gbé àwọn aláìsàn sí àwọn ibi tí wọ́n ti ń tajà, wọ́n á sì bẹ̀ ẹ́ pé kó jẹ́ kí wọ́n fọwọ́ kan wajawaja etí aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀ lásán.+ Ara gbogbo àwọn tó fọwọ́ kàn án sì yá.