-
Jòhánù 9:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Bó ṣe ń kọjá lọ, ó rí ọkùnrin kan tí wọ́n bí ní afọ́jú.
-
-
Jòhánù 9:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, ó tutọ́ sílẹ̀, ó pò ó mọ́ iyẹ̀pẹ̀, ó sì fi pa ojú ọkùnrin náà,+
-