-
Mátíù 16:13-15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Nígbà tó dé agbègbè Kesaríà ti Fílípì, Jésù bi àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé: “Ta ni àwọn èèyàn ń sọ pé Ọmọ èèyàn jẹ́?”+ 14 Wọ́n sọ pé: “Àwọn kan sọ pé Jòhánù Arinibọmi,+ àwọn míì ń sọ pé Èlíjà,+ àwọn míì sì ń sọ pé Jeremáyà tàbí ọ̀kan lára àwọn wòlíì.” 15 Ó wá bi wọ́n pé: “Ẹ̀yin ńkọ́, ta lẹ sọ pé mo jẹ́?”
-