Mátíù 16:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àmọ́ ó yíjú pa dà, ó sì sọ fún Pétérù pé: “Dẹ̀yìn lẹ́yìn mi,* Sátánì! Ohun ìkọ̀sẹ̀ lo jẹ́ fún mi, torí èrò èèyàn lò ń rò, kì í ṣe ti Ọlọ́run.”+
23 Àmọ́ ó yíjú pa dà, ó sì sọ fún Pétérù pé: “Dẹ̀yìn lẹ́yìn mi,* Sátánì! Ohun ìkọ̀sẹ̀ lo jẹ́ fún mi, torí èrò èèyàn lò ń rò, kì í ṣe ti Ọlọ́run.”+