Mátíù 16:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Torí Ọmọ èèyàn máa wá nínú ògo Baba rẹ̀ pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀, ó máa wá san èrè fún kálukú gẹ́gẹ́ bí ìwà rẹ̀.+ Mátíù 25:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Tí Ọmọ èèyàn+ bá dé nínú ògo rẹ̀, tòun ti gbogbo áńgẹ́lì pẹ̀lú rẹ̀, nígbà náà,+ ó máa jókòó sórí ìtẹ́ ògo rẹ̀. 2 Tẹsalóníkà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ ẹ̀yin tí ẹ̀ ń ní ìpọ́njú máa rí ìtura gbà pẹ̀lú wa nígbà ìfihàn Jésù Olúwa+ láti ọ̀run pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ alágbára+
27 Torí Ọmọ èèyàn máa wá nínú ògo Baba rẹ̀ pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀, ó máa wá san èrè fún kálukú gẹ́gẹ́ bí ìwà rẹ̀.+
31 “Tí Ọmọ èèyàn+ bá dé nínú ògo rẹ̀, tòun ti gbogbo áńgẹ́lì pẹ̀lú rẹ̀, nígbà náà,+ ó máa jókòó sórí ìtẹ́ ògo rẹ̀.
7 Àmọ́ ẹ̀yin tí ẹ̀ ń ní ìpọ́njú máa rí ìtura gbà pẹ̀lú wa nígbà ìfihàn Jésù Olúwa+ láti ọ̀run pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ alágbára+