-
Lúùkù 9:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Bí ohùn náà ṣe sọ̀rọ̀, Jésù nìkan ṣoṣo ni wọ́n rí. Àmọ́ wọ́n dákẹ́, wọn ò sì sọ ìkankan nínú àwọn ohun tí wọ́n rí fún ẹnì kankan ní àwọn ọjọ́ yẹn.+
-