Mátíù 17:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé Èlíjà ti wá, wọn ò sì dá a mọ̀, àmọ́ wọ́n ṣe ohun tó wù wọ́n sí i.+ Lọ́nà kan náà, Ọmọ èèyàn máa jìyà lọ́wọ́ wọn.”+
12 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé Èlíjà ti wá, wọn ò sì dá a mọ̀, àmọ́ wọ́n ṣe ohun tó wù wọ́n sí i.+ Lọ́nà kan náà, Ọmọ èèyàn máa jìyà lọ́wọ́ wọn.”+