Lúùkù 18:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ṣùgbọ́n, Jésù pe àwọn ọmọ kéékèèké náà wá sọ́dọ̀ ara rẹ̀, ó ní: “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọdé wá sọ́dọ̀ mi, ẹ má sì dá wọn dúró, torí Ìjọba Ọlọ́run jẹ́ ti irú wọn.+
16 Ṣùgbọ́n, Jésù pe àwọn ọmọ kéékèèké náà wá sọ́dọ̀ ara rẹ̀, ó ní: “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọdé wá sọ́dọ̀ mi, ẹ má sì dá wọn dúró, torí Ìjọba Ọlọ́run jẹ́ ti irú wọn.+