-
Lúùkù 17:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó wá sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé: “Kò sí bí àwọn ohun tó ń fa ìkọ̀sẹ̀ ò ṣe ní wá. Àmọ́, ẹni tí wọ́n tipasẹ̀ rẹ̀ wá gbé! 2 Ó máa sàn fún un gan-an tí wọ́n bá so ọlọ mọ́ ọn lọ́rùn, tí wọ́n sì jù ú sínú òkun ju pé kó mú ọ̀kan nínú àwọn ẹni kékeré yìí kọsẹ̀.+
-