Mátíù 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n mú àwọn ọmọdé wá sọ́dọ̀ rẹ̀, kó lè gbé ọwọ́ rẹ̀ lé wọn, kó sì gbàdúrà, àmọ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn bá wọn wí.+ Lúùkù 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn èèyàn tún ń mú àwọn ọmọ wọn kéékèèké wá sọ́dọ̀ rẹ̀ kó lè fọwọ́ kàn wọ́n, àmọ́ nígbà tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn rí èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í bá wọn wí.+
13 Wọ́n mú àwọn ọmọdé wá sọ́dọ̀ rẹ̀, kó lè gbé ọwọ́ rẹ̀ lé wọn, kó sì gbàdúrà, àmọ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn bá wọn wí.+
15 Àwọn èèyàn tún ń mú àwọn ọmọ wọn kéékèèké wá sọ́dọ̀ rẹ̀ kó lè fọwọ́ kàn wọ́n, àmọ́ nígbà tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn rí èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í bá wọn wí.+