Mátíù 19:25, 26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Nígbà tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn gbọ́ ọ̀rọ̀ yẹn, ó yà wọ́n lẹ́nu gan-an, wọ́n sọ pé: “Ta ló máa wá lè rí ìgbàlà?”+ 26 Jésù bá tẹjú mọ́ wọn, ó sì sọ pé: “Lójú èèyàn, èyí kò ṣeé ṣe, àmọ́ ohun gbogbo ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+ Lúùkù 18:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn tó gbọ́ èyí sọ pé: “Ta ló máa wá lè rígbàlà?”+ 27 Ó sọ pé: “Àwọn ohun tí kò ṣeé ṣe fún èèyàn ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+
25 Nígbà tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn gbọ́ ọ̀rọ̀ yẹn, ó yà wọ́n lẹ́nu gan-an, wọ́n sọ pé: “Ta ló máa wá lè rí ìgbàlà?”+ 26 Jésù bá tẹjú mọ́ wọn, ó sì sọ pé: “Lójú èèyàn, èyí kò ṣeé ṣe, àmọ́ ohun gbogbo ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+
26 Àwọn tó gbọ́ èyí sọ pé: “Ta ló máa wá lè rígbàlà?”+ 27 Ó sọ pé: “Àwọn ohun tí kò ṣeé ṣe fún èèyàn ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+