29 Gbogbo ẹni tó bá sì ti fi àwọn ilé tàbí àwọn arákùnrin, àwọn arábìnrin, bàbá, ìyá, àwọn ọmọ tàbí àwọn ilẹ̀ sílẹ̀ nítorí orúkọ mi máa gba ìlọ́po ọgọ́rùn-ún (100), ó sì máa jogún ìyè àìnípẹ̀kun.+
29 Ó sọ fún wọn pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, kò sí ẹni tó fi ilé sílẹ̀ tàbí ìyàwó, àwọn arákùnrin, àwọn òbí tàbí àwọn ọmọ nítorí Ìjọba Ọlọ́run,+30 tí kò ní gba ìlọ́po-ìlọ́po sí i lásìkò yìí àti ìyè àìnípẹ̀kun nínú ètò àwọn nǹkan tó ń bọ̀.”*+