Mátíù 19:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 “Àmọ́ ọ̀pọ̀ àwọn ẹni àkọ́kọ́ máa di ẹni ìkẹyìn, àwọn ẹni ìkẹyìn sì máa di ẹni àkọ́kọ́.+ Mátíù 20:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Lọ́nà yìí, àwọn ẹni ìkẹyìn máa di ẹni àkọ́kọ́, àwọn ẹni àkọ́kọ́ sì máa di ẹni ìkẹyìn.”+ Lúùkù 13:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ẹ wò ó! àwọn tó jẹ́ ẹni ìkẹyìn máa di ẹni àkọ́kọ́, àwọn tó jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ sì máa di ẹni ìkẹyìn.”+
30 Ẹ wò ó! àwọn tó jẹ́ ẹni ìkẹyìn máa di ẹni àkọ́kọ́, àwọn tó jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ sì máa di ẹni ìkẹyìn.”+