Ìṣe 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó fi idà+ pa Jémíìsì arákùnrin Jòhánù.+ Ìfihàn 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Èmi Jòhánù, arákùnrin yín, tó bá yín pín nínú ìpọ́njú+ àti ìjọba+ àti ìfaradà+ ní ìrẹ́pọ̀ pẹ̀lú Jésù,+ mo wà ní erékùṣù tí wọ́n ń pè ní Pátímọ́sì torí mò ń sọ̀rọ̀ nípa Ọlọ́run, mo sì ń jẹ́rìí nípa Jésù.
9 Èmi Jòhánù, arákùnrin yín, tó bá yín pín nínú ìpọ́njú+ àti ìjọba+ àti ìfaradà+ ní ìrẹ́pọ̀ pẹ̀lú Jésù,+ mo wà ní erékùṣù tí wọ́n ń pè ní Pátímọ́sì torí mò ń sọ̀rọ̀ nípa Ọlọ́run, mo sì ń jẹ́rìí nípa Jésù.