Mátíù 23:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wọ́n fẹ́ràn ibi tó lọ́lá jù níbi oúnjẹ alẹ́ àti ìjókòó iwájú* nínú àwọn sínágọ́gù,+ 7 wọ́n fẹ́ràn kí wọ́n máa kí wọn níbi ọjà, kí àwọn èèyàn sì máa pè wọ́n ní Rábì.* Lúùkù 11:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ẹ gbé, ẹ̀yin Farisí, torí ẹ fẹ́ràn ìjókòó iwájú* nínú sínágọ́gù, ẹ sì fẹ́ràn kí wọ́n máa kí yín níbi ọjà!+
6 Wọ́n fẹ́ràn ibi tó lọ́lá jù níbi oúnjẹ alẹ́ àti ìjókòó iwájú* nínú àwọn sínágọ́gù,+ 7 wọ́n fẹ́ràn kí wọ́n máa kí wọn níbi ọjà, kí àwọn èèyàn sì máa pè wọ́n ní Rábì.*
43 Ẹ gbé, ẹ̀yin Farisí, torí ẹ fẹ́ràn ìjókòó iwájú* nínú sínágọ́gù, ẹ sì fẹ́ràn kí wọ́n máa kí yín níbi ọjà!+